Rejoignez-nous pour un voyage dans le monde des livres!
Ajouter ce livre à l'électronique
Grey
Ecrivez un nouveau commentaire Default profile 50px
Grey
Abonnez-vous pour lire le livre complet ou lisez les premières pages gratuitement!
All characters reduced
Òkú Ààrin-Gbùngbùn - Kì Í Se Gbogbo Awọn Tó Pa Ara Wọn Ni Ẹlẹsìn! - cover

Òkú Ààrin-Gbùngbùn - Kì Í Se Gbogbo Awọn Tó Pa Ara Wọn Ni Ẹlẹsìn!

Owen Jones

Maison d'édition: Tektime

  • 0
  • 0
  • 0

Synopsis

Àdó ólóró buburu kan bú jáde ni ile ìtàjà nla kan ni Baghdad, ti o pa pupọ awọn olùrajà ati osisẹ, ti ọpọlọpọ si yarọ.  Laipẹ, awọn ẹgbẹ bọmbà olupara-ẹni tuntun di awọn ẹniti awọn ọlọpa meje lagbàáyé nwákiri nitoripe wọn ti di ẹrùjẹjẹ fún ara ilu, ti kò ni i se pẹlu ẹsìn tabi òsèlú.  Wọn pe awọn akọsẹmọsẹ ẹrọ ayárabiàsá ti ijọba Ṣháínà ati SAS ti Gẹẹsi lati sèrànwọ, sugbọn njẹ wọn yio le sàwári okùnfà bọmbù tó nsẹlẹ lemọlemọ ki ó tó di wipé ọwọ ara ilu kò ni ká wọn mọ?PUBLISHER: TEKTIME
Disponible depuis: 02/08/2022.

D'autres livres qui pourraient vous intéresser

  • Òkú Ààrin-Gbùngbùn - Kì Í Se Gbogbo Awọn Tó Pa Ara Wọn Ni Ẹlẹsìn! - cover

    Òkú Ààrin-Gbùngbùn - Kì Í Se...

    Owen Jones

    • 0
    • 0
    • 0
    Àdó ólóró buburu kan bú jáde ni ile ìtàjà nla kan ni Baghdad, ti o pa pupọ awọn olùrajà ati osisẹ, ti ọpọlọpọ si yarọ.  Laipẹ, awọn ẹgbẹ bọmbà olupara-ẹni tuntun di awọn ẹniti awọn ọlọpa meje lagbàáyé nwákiri nitoripe wọn ti di ẹrùjẹjẹ fún ara ilu, ti kò ni i se pẹlu ẹsìn tabi òsèlú.  Wọn pe awọn akọsẹmọsẹ ẹrọ ayárabiàsá ti ijọba Ṣháínà ati SAS ti Gẹẹsi lati sèrànwọ, sugbọn njẹ wọn yio le sàwári okùnfà bọmbù tó nsẹlẹ lemọlemọ ki ó tó di wipé ọwọ ara ilu kò ni ká wọn mọ?
    Voir livre